Home iroyin Arákùnrin s’aláìsí lẹ́yìn ọjọ́ kan tí ó jáde pẹ̀lú ipele kíláàsì àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 13, 2019

Arákùnrin s’aláìsí lẹ́yìn ọjọ́ kan tí ó jáde pẹ̀lú ipele kíláàsì àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́.

Arákùnrin kan to n je Al Ameen, ti salaisi ni ana June 12, leyin ojo kan ti o gba ipele akoko ninu eko ni Bayero University Kano.

Ore re @Baffah16 ni o gbe oro naa sioro afefe, o ni

“o hade pelu ipele kilaasi akoko lanaa, o jade laye lonii,ki olorun te emi eri si afefe ire”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…