Home ÀRÒJINLẸ̀ Arábìnrin ń fi ẹ̀hónú hàn láti bẹ̀rẹ̀ ìdájọ́ fún àbúrò rè obìnrin tí agbófinró ọmọ Nàìjíríà fi ipá bá lò pọ̀.
Arábìnrin ń fi ẹ̀hónú hàn láti bẹ̀rẹ̀ ìdájọ́ fún àbúrò rè obìnrin tí agbófinró ọmọ Nàìjíríà fi ipá bá lò pọ̀.
Arabinrin n fi ehonu han lati bere idajo fun aburo re ti agbofinro kan fi ipa ba lo po.
Ninu pépà ti o gbe dani, o ni, Hon. Onwume Chetachi fi ipa ba aburo oun obinrin lo po ni hoteli ti o wa ni Abuja. O ni arakunrin naa ti gbiyanju lati fi owo be awon ki won le gbagbe ejo naa, amo idajo ni awon fe, awon o fe owo.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…