Home òpómúléró “ Ó ti di gbajúmò kí àwọn máa gbè lẹ́yìn ìwà èṣù bíi kí ọkùnrin àti ọkùnrin jọ ni àjọṣepò, obìnrin àti obìnrin jọ ní àjọṣepò, ìṣẹ́yún àti ìjà fún ẹ̀tọ́ abo tó pọ̀ju.

“ Ó ti di gbajúmò kí àwọn máa gbè lẹ́yìn ìwà èṣù bíi kí ọkùnrin àti ọkùnrin jọ ni àjọṣepò, obìnrin àti obìnrin jọ ní àjọṣepò, ìṣẹ́yún àti ìjà fún ẹ̀tọ́ abo tó pọ̀ju.

O soro lori twitter pe “ e ma nifee iyin eeyan ju iyin olorun lo. O ti di gbajumo ti awon eeyan maa gbe leyin iwa ibalopo obinrin si obinrin, ibalopo okunrin si okunrin, iseyun ati ija fun eto abo to poju. O se e se ki won bori idibo. Amo ki lo ma je ere re ti o ba ni gbogbo aye ti o si padanu emi re?”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…