Home iroyin Igbákejì Ààrẹ Sẹ́nètì kúnlẹ̀ láti kí Ààrẹ Buhari.

Igbákejì Ààrẹ Sẹ́nètì kúnlẹ̀ láti kí Ààrẹ Buhari.

Ni ale ana, awon olori tuntun ti national assembly, lo ki Ààrẹ Buhari ni ile aare ni Abuja.

Igabkeji aare senati tuntun, Ovie Omo-Agege, kunle lori ese lati ki Ààrẹ Buhari, lati fun ni owo.

Omo-Agege je omo odun marundinlogota, o je omo Orogun ni Ugheli North local Government ni ipinle Delta.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…