Home ÀRÒJINLẸ̀ Àwọn ọkùnrin mẹ́ta fi ipá bá ọmọ oṣù mẹ́fà lòpọ̀ ní Ìbàdàn.
ÀRÒJINLẸ̀ - orisiirisii - Orisirisi - June 12, 2019

Àwọn ọkùnrin mẹ́ta fi ipá bá ọmọ oṣù mẹ́fà lòpọ̀ ní Ìbàdàn.

Arabinkin to n je @MsKhaddie so lori twitter pe, ara ibise oun mu omo re lo si ile iwosan, nibi ti won ti n duro de dokita ni won sare gbe osu mefa kan wole pe okunrin meta fi ipa ba lo po ni ibadan. Aye nika o.

Ti isele naa ba je ooto, ki owo ijoba ya te awon eni ibi naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…