Home iroyin Ààrẹ Buhari ti yí orúkọ Abuja National stadium sí orúkọ MKO Abiola.

Ààrẹ Buhari ti yí orúkọ Abuja National stadium sí orúkọ MKO Abiola.

Aare Buhari yi yi oruko Abuja national stadium si oruko MKO Abiola.

Aare Buhari ti kede ninu gbolohun to fi kale ni Eagle Square, Abuja, ni ayeye ojo Democracy lonii Wednesday, june 12.

Moshood Kashimawo Abiola MKO ni o bori ni idibo aare ti june 12, 1993 ti olori ologun ana, Ibrahim Babangida to fagi le.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…