Lawan di e̩nìké̩ta ni Nàìjíríà
Ti a ba da ogun odun, a pe, bi a da ogbon osu, a ko. Oni ni ojo naa pe lati di ibo Aare ile igbimo asofin kekere ati nla.
Ibo naa ti waye bayii, Seneto Ahmed Lawan ni o jawe olubori pelu ibo mokandinlogorin (79), nigba ti Seneto Ali Ndume ni ibo mejidinlogbon 28).
Bayii, Ahmed Lawan di ipo keta mu ni orileede yii. Inu gbogbo awon egbe oselu APC si ti n dun fun aseyori naa.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…