Home iroyin Jamb ti dín àmì àti wọ ilé-ìwé gíga sí 160.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 11, 2019

Jamb ti dín àmì àti wọ ilé-ìwé gíga sí 160.

Ipade mokandinlogun ti ofin jamb lori oro ati wole si ile-iwe giga ni orile-ede Naijiria ti din ami ku si 160 lati wo yunifasiti ni odun 2019.

Won se ipinu na ninu ipade ti won se ni Bola Babalakin Auditorium, Gbongan, ipinle Osun ni ojo Tuesday, June 11. Won ni ki ami ati woke si ile iwe giga aladani je 140.

Ti poli maa je 120, ti poli aladani maa je 110.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…