Home iroyin “Ìfẹ̀yìntì Walter Onnoghen wà ní àǹfààní tó dára jù lọ” – National Judicial Council.

“Ìfẹ̀yìntì Walter Onnoghen wà ní àǹfààní tó dára jù lọ” – National Judicial Council.

Igbimo ijoba orile-ede, The National Judicial Council (NJC), ti won fi idi ere re mule pe Aare Buhari ti gba ifeyinti atinuwa Adajo orile-ede Naijiria ana, Justice Walter Onnoghen, won ni o wa ni anfaani to dara ju lo fun orile-ede.

Soji Oye, adari igbimo lori alaye, lo so eyi ninu gbolohun. “Igbimo se ipade ojiji lati gba atinuwa ifeyinto Hon. Mr. Justice Walter Onnoghen, GCON, gege bi Oloye Adajo ipinle Naijiria fun Aare Muhammadu Buhari GCFR.

“Gbigba Ààrẹ yii, wa ni ilana ti igbimo fi kale fun Aare ni April 3,2019. Igbimo naa dupe lowo Aaare fun pe o gba nitori o wa ni anfaani to dara ju lo fun orile-ede.”

Aare ti fun Onnoghen ni idaduro nitori esun pe ikede eke ti dukia, ti Code of Conduct Tribunal fi esun kan an.

Adajo Tanko Muhammad ni won yan ki o wa ni ipo CJN ki ipo naa ma ba sofo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…