Home ÀRÒJINLẸ̀ Ìṣẹ̀lẹ̀ láàárín Wòlíì Suleman àti ọkùnrin tí lu jìbìtì.
ÀRÒJINLẸ̀ - orisiirisii - Orisirisi - June 11, 2019

Ìṣẹ̀lẹ̀ láàárín Wòlíì Suleman àti ọkùnrin tí lu jìbìtì.

Wolii ni omokunrin naa gbe ebun owo to po wa fun oun, oun si beere ise ti o n se amo ko le dahun, oun si ko ebun naa. Leyin ojo meji, awon agbofinro gbe okunrin naa, won si ni ki o ma mu awon lo si ibi ti o ti ha owo si. Ki a ma a mu iyi saju nnkan ti owo le ra lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…