Home ÀRÒJINLẸ̀ Bàbá ọdún ogójì fi ipá bá ọmọ mẹ́tàlá lò pọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Rivers.
ÀRÒJINLẸ̀ - orisiirisii - Orisirisi - June 11, 2019

Bàbá ọdún ogójì fi ipá bá ọmọ mẹ́tàlá lò pọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Rivers.

Omo odun metala n gba itoju lowo ni ile iwosan ni Rivers, leyin ti arakunrin kan won o damo ji gbe fun opolopo wakati, o fi ipa ba lo po, o si da pada peku eje ni gbogbo ara re.

Ajafetoo, Gwamnishu Emefiana Harrison, lo gbe iroyin naa si ori afefe.

O ni:
Baba ogoji odun ji omo odun metala gbe fun opolopo wakati, o fi ipa ba lo po, o si dapada pelu bi o se ri yii.#Endrape.

E fun ni idi ti ko se ye ki a ge nnkan omokunrin re..o ye ki ofin to le wa. Awujo le pinu ati da ejo owo won fun awon ti n ma fi ipa ba awon omo kekere lo po.

Omo na si n gba itoju lowo ni ile iwosan.

A ma rin irin ajo lo si ipinle Rivers lati ri omo naa ati molebi re, ki a ran won lowo, ki a si san owo ile iwosan.

A n fi da awon omo Naijiria loju pe a ma mu asebi naa.

E pin de odo awon ti n se ejo. Won ni ise pupo lati se.

Gwamnishu Emefiena Harrison
DG Behind Bars Right Foundation.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…