Àwọn agbófinró wá ní agbára àti dáàbò orile-ede wa – Ààrẹ Buhari sí àwọn ọmọ Nàìjíríà.
Aare Buhari ti fi da wa loju pe awon agbofinro ati awon ti n daabo wa ni agbara ati daabo orile-ede wa, awon eeyan ati dukia won.
Nigba ti o n fi esi si ero awon Zamfara Advocacy Group ni ojo Aje ninu ipade ni ile ipinle ni Abuja, Ààrẹ ni awon ologun ati olopaa ti n gbe igbese ati wo awon nnkan ti o fa ki o ma si alaafia ni awon agbegbe ati idi ti awon agbe o se le lo si oko.
Aare ni: “ Mo fi dáa yín loju, ojoojumo ni iroyin n kan si mi lati odo awin ti won wa lenu ise ati awon alase ibile. Mo ma se ipade loorekoore peluawon olori awon ti n daabo, won si ti pin awon eeyan won kaakiri awujo.”
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…