Home Entertainment Arákùnrin tí ó kù díẹ̀ kó pàdánù ẹ̀mí rè nínú ìjàmbá ọkọ̀ ti gbé ọ̀kan lára àwọn nọ́ọ̀sì tí ó tójú rè ni ìyàwó.

Arákùnrin tí ó kù díẹ̀ kó pàdánù ẹ̀mí rè nínú ìjàmbá ọkọ̀ ti gbé ọ̀kan lára àwọn nọ́ọ̀sì tí ó tójú rè ni ìyàwó.

Arakunrin ti o ku die ki o padanu emi re ninu ijamba oko, ti pade ololufe re lori ibusun aare.

Anthony T-man n rin irin-ajo ni September 2017 nigbe ti oko ti o wa ninu re se ijamba ni Ife. O fi ara pa pupo, o si pe gan ni ile iwosan.

O fara pa gan ni ese re mejeeji, ti o je pe emarun-un otooto ni won se ise abe fun.

Eru n ba awon eeyan re yoo pada emi re tabi ese re, amo bi olorun se n se ola re,ko padanu ìkankan ninu won.

Ara re si ya, o si gbe Vivian ni iyawo, okan lara awon noosi ti won toju re ni ile iwosan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…