Home orisiirisii “ Ọ̀run ò rọrùn o” arábìnrin ọmọ Nàìjíríà ní òun “kú” òun sì jí padà sí ayé ní òpin ọ̀sẹ̀ tó kọjá.
orisiirisii - June 10, 2019

“ Ọ̀run ò rọrùn o” arábìnrin ọmọ Nàìjíríà ní òun “kú” òun sì jí padà sí ayé ní òpin ọ̀sẹ̀ tó kọjá.

Arabinrin ti di gbajumo lori afefe nitori o ni oun “ku” oun si ji pada ni opin ose to koja.

Won ni, Mhiz Gold Abi, omo Naijiria ti o n gbe ni Casablanca, Morroco, ku, oro naa si ya awon ore re lenu. Awon kan se ofo re lori afefe. Leyin ojo die, o so lori Facebook re pe oun ti pada s’aye.

Gege bi eni ti o de orun ri, o so fun awon ore re lori Facebook pe, “ orun o rorun o”.

O si ti se ileri pe oun ma salaye nnkan ti oju oun ri ni eni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…