Home iroyin Àwọn ọlọ́pàá ìpínlè Rivers mú olè kan, wọ́n sì pa ìkejì nígbà tí wọ́n da ìbọn b’olẹ̀.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 10, 2019

Àwọn ọlọ́pàá ìpínlè Rivers mú olè kan, wọ́n sì pa ìkejì nígbà tí wọ́n da ìbọn b’olẹ̀.

Awon olopaa ipinle Rivers ti mu awon oke ti won gba oko Kexus SUV liwo eni ti o ni oko naa ni agbegbe Government Reserved Area ni Port Harcourt ni Ana june 9.

Gbolohun ti won fi kale ni pe, egbe ole onokunrun-meta naa, se agbako nigba ti won bo si owo awon olopaa ni Tombia extension legbe Market Square ni GRA phase II.

Awon olopaa ati ole naa da ibon b’olẹ̀. Won pa ole kan, won mu okan, iketa si salo pelu oro ibon.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…