Naijiria pàdánù ènìyàn méjìdínlógún lójú e̩s̩è̩
Eniyan ti ko din ni mejidinlogun ni orileede yii tun padanu si inu ijamba moto ajagbe ejo to gbe epo pelu boosi akero kan ni opopona Akure-Owo.
Ilu Oba ile ni isele buruku naa ti sele ni ojo Satide. Nomba awon moto naa ni YLA 25 XU nigba ti ti boosi je GG 873 XM.
Ki Eledu ba wa dawo aburu duro, ki o si maa fi iso re so wa.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…