Home ÀRÒJINLẸ̀ Ìgbìmò ìdìbò máa tẹ̀síwájú lórí ọ̀rọ̀ Atiku ati PDP ní ọjọ́ Ajé.

Ìgbìmò ìdìbò máa tẹ̀síwájú lórí ọ̀rọ̀ Atiku ati PDP ní ọjọ́ Ajé.

Ni ojo Aje, igbimo idibo maa tesiwaju lori oro Peoples Democratic Party ati awon eeyan re fun ibo aare to waye ni February 23.

Amo,a gbo pe ni ojo eti, aare ile ejo ebe, Adajo Zainab Bulkachuwa, ti yan adajo miiran si ipo re, lsti gbo oro naa.

Eyi waye nigba ti Adajo Bulkachuwa yo ara re gege bi omo ebe ati olori paneli eleyan márùn-ún ni May 22, leyin ti Atiku ati PDP ti fi esun kan an pe oun se oju meji. Igbimo naa ti pe akiyesi awon pati ti oro naa kan, ko to di ojo Aje.

Olori osise ofin PDP ati Atiku, DrVy Uzoukwu(SAN), ni o fi idi oro naa mule fun Punch lojo eti, o ni “won ti pe akiyesi wa pe won ma tesiwaju lori oro wa loho aje”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…