Onítíátà Ruth Kadiri ń kí ọkọ rẹ̀ fún ọjọ́ ìbí rẹ̀.
Onitiata Ruth Kadiri n ki oko re, ogbeni Ezerika, fun ojo ibi re lori afefe.
Ruth ati oko re se igbeyawo won ni November 2018, amo ko je ki a ri oju oko re.
O ni: “oko mi atata, oni lojo ibi re. Mo fe ni o wun mi ki o ni ohun to dara ju, amo o ti ni mi. Ku ojo ibi re”
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…