Home Entertainment Ìyàwó onítíátà Kunle Afolayan ti sọ pé, ìṣe abẹ ni oun fi bí àwọn ọmọ òun mẹ́rin.

Ìyàwó onítíátà Kunle Afolayan ti sọ pé, ìṣe abẹ ni oun fi bí àwọn ọmọ òun mẹ́rin.

Iyawo Kunle Afolayan, Desola Afolayan ti salaye pe oun gbiyanju ati yo oyun oun kerin.

Nigba ti o ki omo re abigbeyin, Yiyenitemi, fun ojo ibi re.

O ni ise abe ni oun fi bi awon omo oun meteeta, pe oun o ni owo se ise abe fun omo kerin ni oun se fe yo oyun naa.

Amo bayii, o n dupe pe oun o yo oyun naa, o si lodi si ki a maa yo oyun, o si n gba awon eeyan ni imoran pe ki won ma yo oyun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…