Home ÀṢÀ ÀTI ÌṢE Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Babajide Sanwo-Olu ti ṣe ìbúra fún àwọn akọ̀wé lailai tuntun tí wón ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Babajide Sanwo-Olu ti ṣe ìbúra fún àwọn akọ̀wé lailai tuntun tí wón ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn

Gomina ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu ti se ibura fun akowe lailai (Permanent Secetary) tuntun mẹ́fà tí won sese yan.

Gbolohun ti olori ise(head of service) ipinle eko, Hakeem Muri-Okunola, ni igbese naa ni lati maa tele ofin ipinle lati maa yan awon eeyan tuntun, o si ise won ti bere lati june 1,2019.

Awon akowe lailai tuntun naa ni: Dr Ademujuwa Benhamin Eniayewun, Health Service Commission ; Mr. Olumide Olufolami Erinle, Education District IV; Mrs Okeola Oludara, Education District VI ati Mr. Wasiu Adedamola Akewusola, Ministry of Housing.

Awon to ku ni: Mrs. Yewande Abiodun Falugba, Ministry of Wonen Affairs and Poverty Alleviation ati Mr. Mustapha Abiodun Osi-Efa, Local Government Establishment and Pensions Office.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…