Home iroyin Bọ́m̀bù pa èèyàn mẹ́ta ní Ìpínlẹ̀ Imo.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 7, 2019

Bọ́m̀bù pa èèyàn mẹ́ta ní Ìpínlẹ̀ Imo.

Eeyan meta ti ku leyin ti bombu dun ni agbegbe Eziorsu ni Oguta local government ni ipinle Imo lanaa june 6.

Agbenuso fun olopaa ipinle naa, Orlando Ikeokwu, ti o fi eri idi isele naa mule fun awon oniroyin, ti so oruko awon ti o salaisi, Elvis Ukado, Kasiemobi Uzoma ati Justice Adie.

O ni: “o sele ni ori akitan. Bombu naa si pa awon meteeta sibe, okan lara won n fi owo gba irin naa ki o to lana.

Komisona n fi asiko sofun gbogbo eeyan, pe ti won ba ri irin, ti o jo bombu loju won, ki won tete mu wa fun ayewo.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…