Home Entertainment Yinka Ayefele ní òun ò bí ìbẹta.

Yinka Ayefele ní òun ò bí ìbẹta.

Orisirisi ile ise lori afefe lo ti so pe Yinka Ayefele bi ibeta.

Ayefele ti so lori instagram pe oun o bi ibeta, pe ki won ye so ohun ti won ko mo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…