Home ÀRÒJINLẸ̀ Wọ́n fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n kọlu àwọn mọ̀lẹ́bí Rochas Okorocha.

Wọ́n fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n kọlu àwọn mọ̀lẹ́bí Rochas Okorocha.

Awon egbe olopaa ti ile ijoba lo yabo ile awon molebi gomina tele ti ipinle Imo, Rochas Okorocha, ni ojoru(Wednesday), awon naa ni Ike Okorocha, Jude Okorocha, Gerald Okorocha ati aburo re Okey.

Iroyin fi to wa leti pe, awon olopaa naa ba dukiya won je, won si gun Onyedi Okorocha, omo aburo Rochas Okorocha, won si lo si ile awon aburo re meta( Ike Okorocha, Jude Okorocha ati Gerald Okorocha).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…