Home iroyin Kí àwọn tó ń gbé ní èkó máa pe ago fún àtúnṣe àwọn ihò tó wà ní ojú-àná.

Kí àwọn tó ń gbé ní èkó máa pe ago fún àtúnṣe àwọn ihò tó wà ní ojú-àná.

Gomina ipinle eko, Ogbeni Babajide Sanwo-Olu, ti ni ijoba ma to fi awon ago ti awon to n gbe ni eko le ma pe fun atunse iho ana won.

O so ipinu re lati sisepo pelu awon eniyan ti ipinle fun aseyori ilosiwaju ati eto isakoso re.

O so eyi ni ojo Wednesday nigba ti o gba awon musulumi lalejo ni Ile Eko, Alausa, Ikeja lati se ayeye Eid-el-Fitri ti 2019.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…