Home ÀRÒJINLẸ̀ Ìjọba ti gba ìwé-àṣẹ ìṣe epo ilé-isé márùn-ún.

Ìjọba ti gba ìwé-àṣẹ ìṣe epo ilé-isé márùn-ún.

Departnent of Petroleum Resources (DPR) ti gba ìwé-àṣẹ ise epo, oil mining licenses(OML) ati oil prospecting license (OPL) eyoksn, lowo awon ile-ise márùn-ún.

DPR lo fi gbolohun sile lenii ojobo (Thursday) June 6, won ni ijoba lo fun awon ni ase lati gba ìwé-àṣẹ yii lowo won nitori gbese ti aeon ile-ise naa n je.

Won ni, awon ile-ise naa ni, Summit Oil Internatio al (OPL 206), Express Petroleum and Gas Company (OML 108), Cavendish Petroleum Nigeria (OML 110), Pan Ocean Oil Corporations (OML 98) ati Allied Energy Resources Nigeria (OML 120 and 121).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…