Àkókò Bukola Saraki gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Sẹ́nètì ti dópin.
Aare National Assembly Kejo, Bukola Sakari ti so oro keyin gege bi aaare seneti, ninu apejopo igbimo lonii.
Saraki ni “lonii, a se igbimo apero keyin. O je isegun pe avri igbeyin irinajo naa. O je majemu si nnkan daadaa ti àwọn eeyan le se ti won ba pawopo. O si je okan lara awon asiko ti olorun ma n ran wa leti pe, agbara o si lowo eda alaye kan soso.”
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…