Home iroyin Akẹ́kọ̀ọ́ tí Ìpínlẹ̀ Èkìtì tí gbìyànjú àti gba ẹ̀mí ara ẹ̀ nítorí ó kùnà nínú ìṣe rẹ̀.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 6, 2019

Akẹ́kọ̀ọ́ tí Ìpínlẹ̀ Èkìtì tí gbìyànjú àti gba ẹ̀mí ara ẹ̀ nítorí ó kùnà nínú ìṣe rẹ̀.

Akekoo olodun kerin ni Ekiti State University ti o pelu pupo lara awon to kuna ninu ise kan, ti gbiyanju ati gba emi ara e ni ana ojo Wednesday, June 2019.

Gege bi Lere Olayinka, oluranlowo gomina tele Ayo Fayose, se so, won gbe akekoo naa lo si Ekiti State University Teaching Hospital (EKSUTH), Ado Ekiti nibi awon dokita ti n du emi re lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…