Akọrin Duncan Mighty àti ìyàwó rè ti bí ọmọ kẹta.
Akorin Duncan Mighty ati iyawo re, Vivien, ti bi omo keta.
O so iroyin ayo naa lori instagram.
O ni: “iyawo mi sese b’imo, b’ami dupe lowo Olorun….SUCCEED REIGN MIGHTY…..iya ati omo wa ni alaafia. Oluwa o tobi ju esin lo, iwo ni iwo, jesu alagbara..iwo ni ma sin titi aye mi.”
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…