Home iroyin O ṣe dada, àmọ́ bá ọkọ rẹ ní gbólóhùn inú yàrá – Obasanjo si Aisha Buhari.

O ṣe dada, àmọ́ bá ọkọ rẹ ní gbólóhùn inú yàrá – Obasanjo si Aisha Buhari.

Aare tele, Obasanjo ti gboriyin fun Aisha Buhari nitori o toka si awon kudiekudie ninu ise oko re, Aare Buhari.

Aisha soro nipaana ti ijoba fe gba lati dekun ki awon payan ati ki won ma jale ni ariwa (nothern part) ile Naijiria.

Bi Obasanjo se n gboriyin fun Aisha, o ni ki o ba oko re soro ninu yara nipa awon isele ti ko dun moni ninu to n sele ni Naijiria.

O ni:” o dara pe iyawo aare n soro, mo lero pe o se dada, a ti pe ko ba oko re soro ninu yara. Mo gbagbo pe gbogbo idile, eniyan ati egbe ni won ni eto si igbesi aye. Ojuse gbogbo wa si ni lati gbe aye to rorun. O ye ko je ifokansi gbogbo wa lapapo.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…