Home iroyin Àwọn tó ń ṣo ilé pa ọmọ ọ̀gá wọn obìnrin tó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Ghana nítorí kò san owó oṣù fún wọn.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 4, 2019

Àwọn tó ń ṣo ilé pa ọmọ ọ̀gá wọn obìnrin tó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Ghana nítorí kò san owó oṣù fún wọn.

Awon olopaa ipinle Ondo ti gbe awon okunrin meji ti won n so ile, nitori won pa oga won, Kwakye Kwaku Richards(71 years old) ati omo re, Kwakye Tope(27years old), won je omo ile Ghana, isele naa sele ni ile won ni Ojomo Akintan Estate ni ana Ilesha/Owo ni Ondo.

Awon apayan naa je Hausa ati Fulani, Ayuba Idris, ati Undie Adie, awon mejeeji je omo ogun odun, won jewo pe awon pa oga awon ati omo re, awon si ju oku won sinu ile kan ninu esitati won. Won ni nnkan to fa ti awon fi pa won ni pe oga awon o san owo osu meta fun awon.

Okan lara won ni igbo ati ogun lile(tramadol) ni o fa ti awon fi siwawu,
O ni:
“ni ojo na, a fa igbo a si mu ogun lile, a si pinu lati pa oga wa, bi a se n fun lorun lowo, ni omo re yoju, a si pa oun naa lati bo asiri wa.”

Oga olopaa ti ni won ma gbe won lo si ile-ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…