NAPTIP tí gbe gbajúmò pásítọ̀ fún ẹ̀sùn pé ó fi ipá bá ọmọ lò pọ̀.
National Agency for the Prohibition of Trafficking in Persons(NAPTIP) ti gbe omo odun mejidinlaaadota (48years old) ti o je pasito ni ijo Mountain of Fire and Miracle Church (MFM) ti Gwarinpa ni Abuja.
Won fi esun kan pe o fi ipa ba omo odun merindinlogun (16years old) lo po, omo oru kan si ni omo naa, o si fun omo naa loyun.
Olori awon NAPTIP si ti ni won ma mu oro naa bi o se to, won a si ri pe elese o lo lai jiya.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…