Home Entertainment Anthony Joshua yóò gba owó tó pọ̀ ju ti Andy Ruiz Jnr.

Anthony Joshua yóò gba owó tó pọ̀ ju ti Andy Ruiz Jnr.

Andy Ruiz jr ti o gba ipo eni to lagbara ju lagbaaaye(World Champion), lowo Anthony Joshua, leyin ija ti won ja ni opin ose to koja, yoo gba milionu paun marun-un (5 million pound).

Andy na Anthony ni igba marun-un, ki o to da dabule ni igba keje. Amo bi o tile je pe Andy na Anthony, Anthony yoo gba owo ju Andy lo nitori adehun ti won jo se ni.

Anthony yoo gba ogun milionu paun(20 million pounds), Andy yoo si gba milionu paun marun-un (5million pound).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…