Home ÀRÒJINLẸ̀ Ìròyìn : United States of America tí ń bèrè orúkọ tí àwon èèyàn ń lò lórí afẹ́fẹ́ kí wọ́n tó gba visa.

Ìròyìn : United States of America tí ń bèrè orúkọ tí àwon èèyàn ń lò lórí afẹ́fẹ́ kí wọ́n tó gba visa.

United States ti n bere oruko ti awon eeyan n lo lori afefe (whatsapp,facebook,instragram ati bee bee lo) ki won to le fun awon eeyan ni visa lati lo si ilu won.

Won ti kede ofin tuntun yii ni odun 2017 tele, amo osu ti a wa yii ni won bere si ni mu ofin naa lo, Aare orilede America Donald Trump ni o fi ofin naa lelẹ.

The America Civil Liberties Union ti tako aba yii, won ni yoo fi aye iyasoto(discrimination) sile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…