Home iroyin Mi ò ní lọ sí ayẹyẹ ìgbésípò Sawo-Olu lénìí- Gómìnà Ambode.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - May 29, 2019

Mi ò ní lọ sí ayẹyẹ ìgbésípò Sawo-Olu lénìí- Gómìnà Ambode.

Gomina ilu Eko to fe fi ipo sile, Akinwunmi Ambode ti ni oun o ni lomsi ayeye igbesipo Babajide Sanwo-Olu ti won fe se ni Tafawa Balewa Square lenii May 29.

Ambode so eyi ninu gbolohun ti olori awon akowe re, Habib Aruna gbe kale.

O ni aisinbe oun yoo je ki gomina ti n wole bo le ri opolopo iyi nitori oni l’ojo re
O ni:

“Mo ti gbe gbogbo agbara le gomina ti n wole bo lowo ni ayeye to joju ni ile ilu (State house) lanaa. Ki gbogbo ogo lo si odo Ogbeni Sanwo-olu nitori oun lo ni ojo naa. Mi o ro pe o ye ki a jo pin ogo naa ti mo ba wa nibe.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…