Home iroyin Ilé-ìwé gíga ti Calabar ti dá àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta dúró, nítorí wọ́n fura sí wọn pé wọ́n ń jalè, wọ́n sì tún wà nínú ẹgbẹ́ òkùnkùn.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - May 28, 2019

Ilé-ìwé gíga ti Calabar ti dá àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta dúró, nítorí wọ́n fura sí wọn pé wọ́n ń jalè, wọ́n sì tún wà nínú ẹgbẹ́ òkùnkùn.

Ile iwe giga ti Calabar ti da awon akekoo meta duro nitori won fura si won pe won n jale, won n lu jibiti, won si tun wa ninu egbe okunkun.

Gege bi gbolohun ti alakoso(registrar) won so kale, Mr Moses Abang, o ni alokoso agba(vice chancellor) won, Prof. Zana Akpagu, fi owo si idaduro awon akekoo yii. Oruko awon akekoo naa ni Bassey Divine, o wa ni odun kerin ni eka Sociology, won fi esun kan pe o se jibiti iwe esi idawon GSS, Ofem David, o wa ni odun keta ni eka Theatre, Film and Media Studies, won fi esun kan wi pe o l’owo ninu ole jija.

Akekoo keta, Collins Agbor, o wa ni odun keta ni eka Genetics and Biotech, won fi esun egbe okunkun kan an. Won ni ki awon meteeta yera fun ile iwe titi digba ti won ma fi oju ba awon egbe agbofinro ile iwe naa lati le fi oro wa won lenu wo.

Won si ti so fun awon olori eka won pe ki won mu isele naa ni pataki.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…