Home iroyin Ìgbà mi ìkejì yóò ya àwọn tí wọ́n ń pè mí ní arìndìn “Baba go slow” lẹ́nu -Ààrẹ Buhari

Ìgbà mi ìkejì yóò ya àwọn tí wọ́n ń pè mí ní arìndìn “Baba go slow” lẹ́nu -Ààrẹ Buhari

Aare Buhari ti so pe igba oun ikeji ti yoo bere ni ojo Wednesday, May 29, yoo ya awon ti won n pe oun ni Baba go Slow ni igba akoko oun lenu, nitori isowo ti oun yoo fi sare maa sise.

Aare so eyi ninu ifoworowanilenuwo pataki ti o se pelu NTA ni ale ana. Aare Buhari ni, oun yoo kala pupo, oun yoo si ri pe awon agbofinro ati awon olopaa se ise won daadaa.

Nigba ti won beere boya yoo kala ni igba ikeji re, o ni “ Awon ti won n pe mi ni arindin(baba go slow) maa mo boya mo rindin tabi mi o rindin”

Aare Buhari ni:
“O tumo si pe maa ro awon agbofinro ati awon olopaa lowo pe ki won le mo ibikibi ti won ba ri pe awon eniyan n fi ise won fale, maa se iwadii enikeni ti o n fi ise re fale laaarin awon agbofinro latori DPO doke. IG nikan o le da se, yoo rọ le awon komisona ti awon naa si rọ le awon DPO.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…