Home iroyin Wọ́n na ọ̀daràn kan tí ó jé ọmọ ọdún mẹ́rìnlélógún bí i ẹnímafẹ́kú ni Bayelsa nítorí ó fi ìbọn gba fóònù lọ́wọ́ ọmọbìnrin kan.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - May 27, 2019

Wọ́n na ọ̀daràn kan tí ó jé ọmọ ọdún mẹ́rìnlélógún bí i ẹnímafẹ́kú ni Bayelsa nítorí ó fi ìbọn gba fóònù lọ́wọ́ ọmọbìnrin kan.

Awon egbe ti won yonda ara won fun ida abobo ati egbe vigilante ni agbegbe Akenfa ni ipinle Bayelsa ni won mu odaran omo odun merinlelogun nitori o fi ibon deruba arabirin kan, o si gba foonu re ni ago mejo ale (8:40pm) ni ojo Sunday ni Akenfa NNPC.

Onjiya naa, arabirin Chioma Daminola wi pe, nigba ti oun lo s’ile ni awon okunrin ajoji meji wa ba oun ti won si f’ipa gba foonu oun. Awon odaran naa ni ki Chioma dake nigba ti o beere siimu re.

Odaran ti won mu ti o n je Kelvin Isiah lati Akenfa lo so oruko ikeji re, Edward ti won tu mo si Seselo.

Awon olopaa ti n se eto bi won se maa mu Edward ti foonu naa wa ni owo re.

Won si ti fa eni ti won fura si naa le awon olopaa lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…