Home iroyin MÍNÍSÍTÀ NÍPA Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́PÀÁ TẸ́LẸ̀, YAKUBU LAME TI JẸ́ ỌLỌ́RUN NÍPÈ.

MÍNÍSÍTÀ NÍPA Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́PÀÁ TẸ́LẸ̀, YAKUBU LAME TI JẸ́ ỌLỌ́RUN NÍPÈ.

Minisita nipa oro olopaa tele, Ibrahim Yakubu Lame ti je olorun nipe ni odun merindinlaadorin (66years).

Awon molebi re fi idi eri naa mule wipe o salaisi leyin aisan ojo pipe ni aaro sunday ni Nizamiye Turkish hospital ni Abuja.

Oloogbe Yakubu Lame je eni ti o n lero lati gori ipo gomina ni egbe All Progressive Congress (APC) ni ipinle Bauchi fun idigbo odun 2019, o je senito nigba botched Third Republic ni idun 1992.

Won fi je agba oluranlowo pataki fun aare Olusegun Obasanjo nigba ti won wa lori ipo ni odun 1999, oloogbe aare Musa Yaradua yan gege bi minisita nipa oro olopaa ni december odun 2008.

Won ma se adura fun oloogbe naa ni National mosque ni Abuja lojo sunday ni ago mewaa aaro (10am).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…