Home iroyin “Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò Pàtàkì” pẹ̀lú Ààrẹ Buhari yóò wà lórí afẹ́fẹ́ ní dédé ago mẹ́wàá (10pm) alẹ́ òní.
iroyin - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - May 27, 2019

“Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò Pàtàkì” pẹ̀lú Ààrẹ Buhari yóò wà lórí afẹ́fẹ́ ní dédé ago mẹ́wàá (10pm) alẹ́ òní.

The Nigerian Television Authority(NTA) yoo gbe iforowanilenwo pataki pelu Aare Muhammadu Buhari ni dede ago mewaa (10pm) lori netiwoki won.

Olugbaninimoran lori oro afefe si aare, Femi Adeshina lo so eyi ninu gbolohun to so kale, o ni:
The Nigerian Television Authourity (NTA) lonii, May 29’ 2019, yoo ni ifoworowanilenuwo pataki pelu Aare Muhammadu Buhari ni dede ago mewaa ale (10pm).

Ki gbogbo awon telifison netiwoki ati awon ero amuroyin d’ori afefe ri pe awon n ba ifoworowanilenuwo naa lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…