Home ÀKỌ̀TUN Buhari ati Osinbajo gbo̩dò̩ jé̩wó̩ dúkìá wo̩n fáráyé
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 25, 2019

Buhari ati Osinbajo gbo̩dò̩ jé̩wó̩ dúkìá wo̩n fáráyé

Ajo to n ye dukia awon osise ijoba wo ki won to de ori oye (Code of conduct bureau) ti fi towo-towo ran Aare Muhamnadu Buhari leti pe, ki won ma se gbagbe lati jewo dukia won fun ajo yii, ki o to di ojo kejidinlogbon osu ti a wa yii.
Aare nikan ko lo n jewo dukia gage bi o se wa ninu iwe ofin wa, igbakeji Aare, Olori ile-igbimo asofin kekere ati agba, gomina, igbakeji re, olori ile-igbimo asofin ipinle kookan, olori ile-ejo ati awon oga ilèese ijoba kankan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…