Home ÀKỌ̀TUN Ọlọ́pàá Ìlú Ògùn Gbé Arákùnrin Kan Fún Ẹ̀sùn Pé Ó Pa Bàbà Rẹ̀.
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 20, 2019

Ọlọ́pàá Ìlú Ògùn Gbé Arákùnrin Kan Fún Ẹ̀sùn Pé Ó Pa Bàbà Rẹ̀.

Olopaa ilu Ogun gbe arakunrin Babatunde Olagesin fun esun pie o pa baba re, Taiwo Olagesin, pelu ada nitori won jo ni gbolohun aso ni ile won ni Ijoko ni ojo kefa Monday osu May.
Iroyin fi towa leti pe Babatunde so fun baba re pe oun fe jade ni dede ago mefa aaro pe oun lo si Oshodi, amo baba re o fun laye lati lo tori o fe ki won jo lo si ibikan.

Taiwo ti gbogbo ilekun ile, bi won se bere gbolohun aso niyen, Taiwo fi ibinu fa ada yo lati fi s’eruba omo re, amo bi Babatunde se n gbiyanju lati gba ada naa ni o sesi fi ada la inu baba re.
Awon ara ile ati adugbo si kepe awon olopaa lati wa gbe Babatunde.
DSP Abimbola Oyeyemi lo fi idi eri isele naa mule, o si ni won a to gbe ejo naa lo si ile-ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…