Sé̩nétò̩ fo̩wó̩ si June 12
Awon ile igbimo asofin ti fowo si ojo kejila osu kefa odoodun gage bii ayajo ijoba awa-ara-wa.
Won ni awon fi eleyii se aponle Oloogbe Moshood Abiola to wole ibo Aare odun 1993 ti ijoba ologun Ibrahim Babangida wogi le.
Won ni ko si idi pataki kankan fun ojo kokandinlogbon osu karun-un ti a maa n se ayajo naa tele. Ofin wa gun-un lati oni lo pe ojo kejila osu kefa ni ki o maa je ojo sinmi igbe ijoba fun ara wa.
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…