Home iroyin E gbani, e la’ja! Agunbaniro d’ero atimole
iroyin - Orisirisi - May 14, 2019

E gbani, e la’ja! Agunbaniro d’ero atimole

Okunrin agunbaniro kan ni won ti taari si atimole bayii o, latari pe won ni o tanu baa won alase yunifasiti kan, lori bi nnkan se n lo ni ile eko naa.
Paapaa, won ni agunbaniro naa, Chijioke Nnamani se gbenugbenu lori oga fafiti ohun.

Lori ero alatagba Twitter ni awon eeyan ti n so pe ki won tu ajunbaniro naa sile, eyi ti won pe ni ‘E tu Nnamani sile” (FreeNnamani).
Sugbon sa o, won ni arakunrin naa yoo foju ba ile ejo ni ilu Awka.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…