Home iroyin Awọn kan n gbadura iku fun mi tori ohun ti mo sọ lori Yahoo boys – Eldee
iroyin - LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - May 14, 2019

Awọn kan n gbadura iku fun mi tori ohun ti mo sọ lori Yahoo boys – Eldee

AKorin kan ti orukoo re n je Eldee ti so pe opo awon omo Nigeria lo ti n gbadura iku fun oun leyin ti oun soro lori eru(fraud) nigba ti o je pe ori ero alatagba lo ti so.
Akorin naa soro lorii bi won se mu onkorin “Issa Goal”, Naira Marley, ati akegbe re, Zlatan Ibile, awon ti won ni Yahoo Yahoo kii se nnkan buburu.

Eldee ni eru ba oun nigba ti oun ri pe opo awon Omo Nigeria ni o gbiyanju lati ri i bi oun to dara.

O ni bi oun se soro yii mu ki awon eniyan kan maa ro iku si oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…