Home ÀKỌ̀TUN Àjo̩ òsìsé̩ gbé pé̩ré̩gi kaná pè̩lú Ngige
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 13, 2019

Àjo̩ òsìsé̩ gbé pé̩ré̩gi kaná pè̩lú Ngige

Ajo awon ossie orileede Naijiria (NLC) ti wo sokoto Kan naa pelu minisita won, Dokita Chris Ngige.
Ede aiyede waye laarin won ni ose to koja nigba ti ajo osise ko iwode lo si ile Ngige ni ose to koja, ibi iwode naa ni awon janduku ti le won kuro ti won si se die lese ninu won.
Eyi gan-an lo da gbomi si omo ko too sile laarin won. Ajo awon osise ti wa bere iwode olojo mewaa lonii lori Ngige. Won ni ki Ngige fi ipo sile laarin ojo mewaa pere nitori pe bi iwode se bere bayii ni Naijiria lo maa te siwaju ni oke okun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…