Home ÀKỌ̀TUN Sún ke̩e̩re̩, fà ke̩e̩re̩ mú òkú àti alààyè ní ò̩nà Eko sí Ibadan
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 11, 2019

Sún ke̩e̩re̩, fà ke̩e̩re̩ mú òkú àti alààyè ní ò̩nà Eko sí Ibadan

Yoruba bo, won ni, “ibi ti eniyan ba rin de lo maa ti oran mo”. Aseju sun keere, fa keere opopona Eko si Ibadan ko je ki awon olugbe Mowe, Ibafo ,Magboro ati awon arinrinajo le jade kuro l’Eko ati awon to n wole si Eko mo odo to won maa da orunla si.
Ojoojumo ni isele kan tabi meji n sele ti o si n je ki awon eniyan wole loru.
Eyi to sele lati ijeeta, ojo kejo, osu ti a wa yii tun le kenka. O le de bi wi pe o mu moto to n egbe oku duro sojukan. O mu gbogbo eni to n fese rin, awon olokada gan an ko ribi gba.
Eyi lo mu ki ogbeni Bisi Kazeem to je alukoro ajo eso oju ona (FRSC) kede faraye pe ki awon onimoto wa ona miran gba.
Bi awon Musulumi se n sinu ni won n je saari ni ona naa. Bi o se n mu eni to n lo, lo mu eni to n bo.
Inu awon ara ilu gan an ko dun si awon Julius Berger to n sise ona naa. Won ni won ti fere lo to osu mejo ni oju Kan naa ti o si je oun to buru ju ni ilu ti loba to si ni ijoye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…