Home ÀKỌ̀TUN PDP ń ko̩ lu òfin ìbani-lórúko̩-je̩ – Garba Shehu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 11, 2019

PDP ń ko̩ lu òfin ìbani-lórúko̩-je̩ – Garba Shehu

Olubanidamoran pataki lori iroyin to n sise fun Aare Mohammadu Buhari, Ogbeni Garba Shehu ni o n salaye yii ni ilu Abuja nigba ti o n ba awon oniroyin soro.
O ni ti egbe naa ba ti padanu ejo kan ni won maa bere si ni yo suuti ete si Aare ati awon olu ba Aare sise po pelu awon adajo ile-ejo.
O ni eleyii buru pupo, o si ta ko ofin ile wa. O ni ti ile ise Aare ba maa n da si oro ile-ejo, ko ye ki egbe oselu APC maa padanu ejo kankan.
Ogbeni Garba Shehu ni ki won soro gidi gan-an, ki won ye fi oro koro ko ile-ise Aare lorun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…