Home iroyin Oro godo-gain: Arakunrin n gbero lati ko iyawo re sile lojo keji igbeyawo.
iroyin - LÁGBO ÀRÍYÁ - May 11, 2019

Oro godo-gain: Arakunrin n gbero lati ko iyawo re sile lojo keji igbeyawo.

Arakunrin kan ni orile-ede Ghana ni o ti n gbero lati ko iyawo re sile leyin wakati merin le logun(24 hours) ti won se igbeyawo.

Okunrin naa ni oun fe ko o sile nitori pe kii se irisi ti oun ri ko to di pe oun fe e ni oun ri ni ale ojo igbeyawo awon.

Gege bi o ti so, o ni oun ati iyawo oun ni adeun pe awon ko ni sumo ara awon titi di ale igbeyawo.
O ni gbogbo igba ti awon wa po, oun ma n ri i gege bi eni to ni idi nla ni, ti o si je pe eyi lo je ki oun nife re.

O ni sugbon ni ale igbeyawo awon ni oun ri i pe eyin re o tobi to bi oun se lero.
O ni bee, akasu bamba ti oun ro pew a leyin re gan-an ni o wu oun lara re, ati pe igba ti oun si ti ri i pe ko si nkankan nbe ni ko ti wu oun mo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…