Home Orisirisi N ko mo eni to n je Tonto Dikeh – CDQ
Orisirisi - May 11, 2019

N ko mo eni to n je Tonto Dikeh – CDQ

Olamide Yusuf

Tonto Dikeh
Gbajugbaja olorin ti a mo si CDQ ti so pe oun ko mo eni ti n je Tonto Dikeh ri.

Gege bi iroyin, o so ninu video to se lori ero alatagba Intagram, nigba ti okan lara awon ololufe re wi pe ko soro nipa Tonto Dikeh.
O ni oun o mo eni ton je Tonto Dikeh, o si tun kilo fun awon ololufe re pe ki won ma mu oro arabinrin naa wa si etigbo oun mo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…