Home iroyin Moto pa omo odun merin si iwaju ile awon obi re.
iroyin - May 11, 2019

Moto pa omo odun merin si iwaju ile awon obi re.

A kii gbe eni ka forum ro, bii ti omodekunrin kan ni ilu Eko ko o.
Idi ni pe moto kan ya won ilea won obi re, to si pa a sibe.
Awako moto naa ti oruko re n je Adenowo Adeyiga ni won ni o n bo lati I jegun nigbati bireeki oko re ja ti o si lo ya ba omo naa ni ile won ni Alagbado.

Won ti gbe direba akoranbani naa lo sile ejo.
O ni oun ko jebi, ti adajo si ti sun igbejo naa si ojo keedogun osu kefa odun 2019.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…